Bibeli Mimo - TWOGBS

Find on Amazon Buy on Bookshop.org

Affiliate links: we may earn a commission on purchases.

About this book

BÍBÉLÌ MÍMÓ̩ ONÍTUMÒ̩ MÁJÈ̩MÚ LÁÉLÁÉ ÀTI TITUN ©2009 © Revised 2010 © TWoGBs 2009-2010 No part of this Bible may be reproduced by photocopying or by mechanical or by electronics means or in any other form without prior written permision from the Publisher iBooks Author Version ISBN 978-1-908470-05-8 BÍBÉLÌ MÍMÓ̩ ONÍTUMÒ̩ Typeset and Printed by The Word & The Word of God Bible Society The Word of God Bible Society Charity Registered No. 1133009 Company No. 6824905 [email protected] === Isé̩ yìí jé̩ ogún The Word of God Bible Society, a KÒ sì gbo̩dò̩ dà á ko̩ fún eniké̩ni tàbí fún ò̩ré̩. Lò ó bí i ìwé tí ó jé̩ wí pé e̩nìkan-soso ni ó lè lò ó lé̩è̩kan. Má s̩e lò ó ju nínú kò̩mpútà kan-soso lo̩ lé̩è̩kan. A kò fi às̩e̩ fún e̩niké̩ni láti s̩e àtúntè̩, tabí láti s̩e àdàko̩, tàbí láti tún Bíbélì Mímo̩ Onítumò̩ tí a kà yìí kà sí inú kò̩pútà, tàbí kí á ká a sí inú káséè̩tì (cassette), è̩ro-ìbánisò̩rò̩-alágbéká, ero̩-orin-alágbéká, tàbí CD/DVD, tàbí irúfé̩ ero̩ tí a lè fi nkan tàbí ò̩rò̩ pamó̩ sí; tàbí fún gbígbó̩ lòdì sí èròǹgbà ti irúfé̩ mìíran tí a so̩, tàbí tí a kò so̩ nígbà pínpín ò̩rò̩ Bíbelì yìí nigbà tí a tà á. E̩ni tí ó bá s̩e lòdì sí èyí fi hàn gban̄gba wí pé kò fé̩ ìtànká ìhìn-rere. Owó tí a bá rí nínú títa Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ yìí ni a yóó lò fún títè̩síwájú ìpín-fún-ni Ò̩rò̩ Olórun. Fi e̩nu kò pèlú ìlérí fún Jésù Krístì Olúwa wí pé o ra ètò Bíbélì yìí àti kíkà rè̩ ló̩nà è̩tó̩, àti wí pé o kò ní fi fún e̩niké̩ni ló̩nà àìtó̩. A ń retí bí O̩ló̩run bá ti fi sí yín ní o̩kàn: ò̩rò̩ ìgba-ni-ní-yànjú, ìrànló̩wó̩, è̩bùn, owó, ètò è̩ro kò̩mpútà fún Bíbélì yìí, tàbí ohun èlò fún às̩eyo̩rí àti ìtè̩síwájú is̩é̩ Bíbélì Onítumò̩ yìí láti ò̩dò̩ yín. Gbogbo onírúurú tàbí irúfé̩ àdàko̩ ni òfin yìí lòdì sí. 'Sí òfin àti sí è̩rí, bí wo̩n kò bá so̩ gé̩gé̩ bíi ò̩rò̩ yìí; nítorí tí kò sí ìmó̩lè̩ nínú wo̩n ni' (Ìsáíàh 8:20). === These files are the property of The Word of God Bible Society and may NOT be copied or shared with

What genre is Bibeli Mimo - TWOGBS?

It sits on the Religion shelves.

Who wrote Bibeli Mimo - TWOGBS?

The Word & The Word of God Bible Society.

Bibeli Mimo - TWOGBS Check price →